Connect with us

BIRTHDAY

YORUBA COUNCIL OF YOUTHS WORLDWIDE (YCYW )OGUN STATE COUNCIL, KI BABA WA HRM OBA (PROF.) ABDUL KABIR ADEYEMI, (LÁNLÈGÈ ẸKÙN ii) OLOTA OF OTA ÀWÓRÌ KINGDOM KU ORÍIRE ỌJỌ IBI WỌ́N LÓNÌ

Published

on

YORUBA COUNCIL OF YOUTHS WORLDWIDE (YCYW )OGUN STATE COUNCIL, KI BABA WA HRM OBA (PROF.) ABDUL KABIR ADEYEMI, (LÁNLÈGÈ ẸKÙN ii) OLOTA OF OTA ÀWÓRÌ KINGDOM KU ORÍIRE ỌJỌ IBI WỌ́N LÓNÌ

Ni Orúkọ Gbogbọ Igbimọ Ọdọ Yorùbá Lágbayé ẹka tí Ipinlẹ Ogun labẹ Àṣẹ Alaga wa Hon. Sunday Adebowale a ki HRM Oba (Prof.) Abdul Kabir Adeyemi Obalanlege. ,(Lanlege Ekun ii) .Olota of Ota Awori Kingdom, ku ayẹyẹ ọjọ ìbí wọn loni ọjọ keji dinlogbon Oṣu kẹjo (August), ọdún ọ̀kan-le-ni-okòó le ni ẹgbàá (2021)

A si gba ni adura npe ki ọlọrun tún bọ máa b’awa lọra ẹmi yin ninu ọlá, ninu ipo, ninu ọgbọn àti oye, paapa julọ ninu àìkú baálẹ̀ ọrọ. ọdọọdún làá nri orógbó, ọdọọdún làá nri arẹsà, ọdọọdún làá nri ọmọ obi lori atẹ, ọdọọdún la o maa ri yin ba, t’ẹbi, t’ara ati ojulumọ

Lẹẹkansi ẹku oriire ọjọ ibi yin loni, ẹmi yin aṣe púpọ ọdún láyé, lágbára ọlọrun àti àwọn tó tẹ ilẹ Awori ati yorùbá dó. Àṣẹ!

A si tun fi akoko yi dupẹ lọwọ yin Lẹẹkansi fún ipa ribiribi ti ẹtì nko ninu ìdàgbàsókè, iṣọkan ati ìgbéga ipinle Ogun ,ilẹ Yorùbá ati gbogbo orilẹ-ède Naijiria lapapọ paapajulọ ni ẹka ọdọ, Asa ati ise, ẹ ṣe gan adupẹ, ki ọlọrun bawa kun yin lọwọ

Ọmọ Yorùbá ni mí, Ọmọ kaarọ ojiire!

Fún igbimọ ọdọ ipinlẹ ogun

KABIYESI O

E-signed

Hon. Sunday Adebowale

Chairman, YCYW Ogun State Council

28/8/2021

Click to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *